Publisher's Synopsis
Aremu enjoyed the happiness of a rich family before the demise of his father when he was only a young boy in elementary school. He was thereafter confronted with various challenges of life. His relentless effort was eventually rewarded leading to a rich, beautiful life which led to celebration. The book is indeed a product of a wordsmith. Aremu weaves life experiences just with words as a blacksmith forges working implements.
It is full of wits, anecdotes and humor peculiar of the Yoruba language and culture.The book also contains questions and answers part to help the understanding of Yoruba students. It is recommended for all lovers of Yoruba Language. YORUBA
Àrè?mú pàdánù bàbá rè? nígbà tó wà ní màjè?sín, o sì ní ọ`pọ`lọpọ` ìdojúkọ àti ìrírí ayé nínú ìrìn àjò rè? láti gòkè àgbà. Ṣe ìrírí ayé kìí fini títí kó fini pa, ọgbọ´n ló fi nkọ´ ni. Àrè?mú kò rè?wè?sì nínú làásìgbò yìí, ó sì jèrè ìforítì. Inú ẹni kìí dùn ká paá mọ´ra. Ẹsè? tó nà báyìí, ijó ló fàá. Kò sóhun tóle tí kìí dè?. Ọ`rọ` ni Àrè?mú fi rọ ìrírí ayé kalè? bí ìgbà ti alágbè?dẹ rọ ọkọ´ àti àdá nínú ìwé yìí. Bé?è?ni àsà àti ìṣe Yorùbá pè?lú è?kọ´ àti àwàdà ọ`kan-ò-jọ`kan kún inú Àrè?mú Alágbè?dẹ Ọ`rọ`. Bákannáa ni àwọn ìbéèrè wà lórí ìwé yìí fún àwọn aké?kọ`ọ´. Àkàgbádun sìni fún gbogbo ènìyàn.